Friday, August 28, 2009

IFE (LOVE) BY OTAIBAYOMI

Ogundele Samuel Abayomi
IFE (LOVE)

IFE NI AKOJA OFIN NI ILE YORUBA,HMM IFE!IFE!IFE!! ORO IFE NI AGBARA PUPO NI IGBESI AYE(LIFE) AWA EDA (PEOPLE).

EYIN ARA MI E DAKUN DABO E FI IYE (THOUGHT) DE NU, E FI IFE(LOVE) BA OLUGBE(NEIGBHOUR) YIN LO NINU GBOGBO NKAN TI E BA N SE NIT...ORIPE ASEGBE KAN KO SI NI AYE.

IWE MIMO (BIBLE), FI YE MI WIPE TI IWO BA FURUGBIN KIUN, KIUN NI IWO NAA YOO KA (WHAT EVER YOU SOW, YOU WILL REAP)

No comments:

Post a Comment